alagbara aye
aye a tan ooo
eni loni egbo
awon to shana
won o si moo
igba loni igba nlo
bawo lo si ire
yo san esan
olojo die laye
ma gba ona kan kan
ofefe laye asan
maje ko wo e leje
igba o lo bi orere
o f'ogun odun sebi
yio fa da gbaro
ke ya lomo pe otipa
ida pani yio ti'da ku o